www.awikonko.com.ng
Open in
urlscan Pro
188.114.96.3
Public Scan
Submitted URL: http://awikonko.com.ng/
Effective URL: https://www.awikonko.com.ng/
Submission: On October 24 via api from US — Scanned from NL
Effective URL: https://www.awikonko.com.ng/
Submission: On October 24 via api from US — Scanned from NL
Form analysis
2 forms found in the DOMGET /search

Name: contact-form —

Name

Email *

Message *

<textarea class="contact-form-email-message" cols="25" id="ContactForm1_contact-form-email-message" name="email-message" rows="5"></textarea>

Text Content
IROYIN AWIKONKO * Oct 24, 2024 * * * * * * * * * GBÀGEDE * NÍPA WA * Ẹ BÁ WA DÉLÉ MenuGBÀGEDENÍPA WAẸ BÁ WA DÉLÉ Adnaira[N]x * GBÀGEDE * KÍ LẸ FẸ́Ẹ́ MỌ̀? * ÌBÉÈRÈ * Ẹ BÁ WA DÉLÉ * NÍPA WA * ÀWỌN ÒṢÌṢẸ́ WA * ÌLÉPA ÀTI ÀFOJÚSÙN * ÌRÒYÌN TUNTUN * ÌPOLÓWÓ * ÌRÒYÌN * ÒṢÈLÚ * KÀYÉÉFÌ * Ẹ̀SÌN * LÁWÙJỌ WA * FÚNKẸ́ ANÍMÁṢÁUN * ÈTÒ ÀÀBÒ * KÁŃSẸ́LỌ̀ * ÌKÉDE PÀTÀKÌ MenuGBÀGEDE- KÍ LẸ FẸ́Ẹ́ MỌ̀?-- ÌBÉÈRÈ-- Ẹ BÁ WA DÉLÉ-- NÍPA WA-- ÀWỌN ÒṢÌṢẸ́ WA- ÌLÉPA ÀTI ÀFOJÚSÙN- ÌRÒYÌN TUNTUNÌPOLÓWÓÌRÒYÌN- ÒṢÈLÚ- KÀYÉÉFÌ- Ẹ̀SÌNLÁWÙJỌ WAFÚNKẸ́ ANÍMÁṢÁUNÈTÒ ÀÀBÒKÁŃSẸ́LỌ̀ÌKÉDE PÀTÀKÌ LÉRÉFÈÉ * * Kwara ELERIN TILUU ERIN-ILE GBỌPA AṢẸ NI KWARA * Kwara IJỌBA KWARA BẸRẸ DIDA ỌDA IKẸYIN SI OPOPONA POST OFFICE, ỌJA ỌBA SI ẸMIR * Kwara OJULOWO OPOPONA TO JA GEERE NI ỌNA ABAYỌ SI ETO ỌRỌ AJE TO DARA - IJỌBA KWARA * Adron ILEEṢẸ ADRON HOMES ṢAFIHAN 'LEMON FRIDAY' PẸLU ANFAANI ALARAGBAYIDA FUN ANFAANI MẸKUNNU * ISE AGBE OUNJẸ YANTURU NI KWARA, IRỌRUN ỌMỌ NAIJIRIA Kwara ELERIN TILUU ERIN-ILE GBỌPA AṢẸ NI KWARA IROYIN AWIKONKOỌWARA 19, 2024 Elerin tiluu Erin-Ile nipinlẹ Kwara, Ọba Adesoye Adebọwale Jimọh ti gbọpa aṣẹ ati iwe ẹri.Gomina Abd... Kwara IJỌBA KWARA BẸRẸ DIDA ỌDA IKẸYIN SI OPOPONA POST OFFICE, ỌJA ỌBA SI ẸMIR IROYIN AWIKONKOỌWARA 19, 2024 Lasiko ti a pari akojọpọ iroyin yii, awọn agbaṣẹṣe ti bẹrẹ sii da ọda to kẹyin si opopona Post Offic... Kwara OJULOWO OPOPONA TO JA GEERE NI ỌNA ABAYỌ SI ETO ỌRỌ AJE TO DARA - IJỌBA KWARA IROYIN AWIKONKOỌWARA 19, 2024 Ijọba ipinlẹ ti ṣe ileri wi pe gbogbo awọn opopona to wa kaakiri ipinlẹ naa ni wọn yoo ṣe ni ti igba... Adron ILEEṢẸ ADRON HOMES ṢAFIHAN 'LEMON FRIDAY' PẸLU ANFAANI ALARAGBAYIDA FUN ANFAANI MẸKUNNU IROYIN AWIKONKOỌWARA 17, 2024 Ileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited ti ṣfihan agbekalẹ ọtun fun igbadun araalu, paapaa awọn on... ISE AGBE OUNJẸ YANTURU NI KWARA, IRỌRUN ỌMỌ NAIJIRIA IROYIN AWIKONKOỌWARA 17, 2024 Pẹlu bi nnkan ṣe n lọ bayii, ipinlẹ Kwara ti n wa lara awọn ipinlẹ ti yoo fọkan ọmọ Naijiria balẹ ni... Adnaira[N]x ÒṢÈLÚ WOO SI I IDIBO: ORIIRE NLA LO WỌLE TỌ APC NI KWARA - ABDULRAZAQ IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 23, 2024 Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti ba gbogbo awọn oludije to jawe olubori sipo alaga kansu nipinlẹ naa yọ, to si tun ki wọn ku oriire.Lopin ọsẹ to kọja yii ni eto idibo sipo alaga kansu kaakiri ijọba ibilẹ mẹrindinlogun to wa ni Kw... Ẹ FỌKÀNBALẸ̀, ÀWỌN ÀṢEYỌRÍ ÀKÀNṢE IṢẸ́ ÌDÀGBÀSÓKÈ WA YÓÒ FỌHÙN FẸ́GBẸ́ APC NÍNÚ ÈTÒ ÌDÌBÒ ÌJỌBA ÌBÍLẸ̀ - ABDULRAZAQ FỌKÀN ÀWỌN OLÙDÍJE BALẸ̀ IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 20, 2024 Bi eto idibo ijọba ibilẹ kaakiri orileede Naijiria ṣe sunmọ etile, Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti fọkan gbogbo awọn oludije sipo oṣelu lawọn ijọba ibilẹ kaakiri balẹ.Gomina AbdulRazaq sọ pe awọn akanṣe iṣẹ idagbasoke toun ti ṣe gẹgẹ... WAHALA DE! GBENGA MAKANJUỌLA FẸGBẸ OṢELU PDP SILẸ NI KWARA, O TUN KO AWỌN ỌMỌ ẸYIN RẸ WỌ APC IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 19, 2024 Idarudapọ lo tun wọnu ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP nipinlẹ Kwara pẹlu bi gbajugbaja oloṣelu nni, Gbenga Makanjuọla ṣe fẹgbẹ naa silẹ, to si ba ẹgbẹ miran lọ. Ko si nnkan meji to mu ki iṣẹlẹ ọhun jẹ kayeefi bi ko ṣe bi Makanjuọla to ... JONATHAN TU AṢIRI IDI TO FI YỌ SANUSI NIPO GẸGẸ BI GOMINA CBN IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 27, 2024 Aarẹ tẹlẹri lorileede Naijiria, Goodluck Ebele Jonathan, l'Ọjọbọ, ọsẹ yii ti sọ awọn aṣiri to ṣokunkun sawọn ọmọ Naijiria lori idi pataki ti ijọba rẹ fi yọ Ọmọwe Sanusi Lamido Sanusi nipo gẹgẹ bii gomina ile ifowopamọ agba ilẹ naa, CBN Jonathan ... SARAKI KO LẸNU ỌRỌ LORI ETO IDIBO IJỌBA IBILẸ TO WAYE NI KWARA - IJỌBA IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 27, 2024 Ijọba Kwara ti sọ pe aarẹ ile igbimọ aṣofin agba lorileede Naijiria tẹlẹ, Sẹnetọ Bukọla Saraki ko lẹnu ọrọ lati sọrọ lori abajade eto idibo ijọba ibilẹ to waye kọja, nibi ti ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress ti jawe olubori.Ijọba sọ pe gbogbo ọna ... IDIBO: ORIIRE NLA LO WỌLE TỌ APC NI KWARA - ABDULRAZAQ IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 23, 2024 Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti ba gbogbo awọn oludije to jawe olubori sipo alaga kansu nipinlẹ naa yọ, to si tun ki wọn ku oriire.Lopin ọsẹ to kọja yii ni eto idibo sipo alaga kansu kaakiri ijọba ibilẹ mẹrindinlogun to wa ni Kw... Ẹ FỌKÀNBALẸ̀, ÀWỌN ÀṢEYỌRÍ ÀKÀNṢE IṢẸ́ ÌDÀGBÀSÓKÈ WA YÓÒ FỌHÙN FẸ́GBẸ́ APC NÍNÚ ÈTÒ ÌDÌBÒ ÌJỌBA ÌBÍLẸ̀ - ABDULRAZAQ FỌKÀN ÀWỌN OLÙDÍJE BALẸ̀ IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 20, 2024 Bi eto idibo ijọba ibilẹ kaakiri orileede Naijiria ṣe sunmọ etile, Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti fọkan gbogbo awọn oludije sipo oṣelu lawọn ijọba ibilẹ kaakiri balẹ.Gomina AbdulRazaq sọ pe awọn akanṣe iṣẹ idagbasoke toun ti ṣe gẹgẹ... WAHALA DE! GBENGA MAKANJUỌLA FẸGBẸ OṢELU PDP SILẸ NI KWARA, O TUN KO AWỌN ỌMỌ ẸYIN RẸ WỌ APC IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 19, 2024 Idarudapọ lo tun wọnu ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP nipinlẹ Kwara pẹlu bi gbajugbaja oloṣelu nni, Gbenga Makanjuọla ṣe fẹgbẹ naa silẹ, to si ba ẹgbẹ miran lọ. Ko si nnkan meji to mu ki iṣẹlẹ ọhun jẹ kayeefi bi ko ṣe bi Makanjuọla to ... JONATHAN TU AṢIRI IDI TO FI YỌ SANUSI NIPO GẸGẸ BI GOMINA CBN IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 27, 2024 Aarẹ tẹlẹri lorileede Naijiria, Goodluck Ebele Jonathan, l'Ọjọbọ, ọsẹ yii ti sọ awọn aṣiri to ṣokunkun sawọn ọmọ Naijiria lori idi pataki ti ijọba rẹ fi yọ Ọmọwe Sanusi Lamido Sanusi nipo gẹgẹ bii gomina ile ifowopamọ agba ilẹ naa, CBN Jonathan ... SARAKI KO LẸNU ỌRỌ LORI ETO IDIBO IJỌBA IBILẸ TO WAYE NI KWARA - IJỌBA IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 27, 2024 Ijọba Kwara ti sọ pe aarẹ ile igbimọ aṣofin agba lorileede Naijiria tẹlẹ, Sẹnetọ Bukọla Saraki ko lẹnu ọrọ lati sọrọ lori abajade eto idibo ijọba ibilẹ to waye kọja, nibi ti ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress ti jawe olubori.Ijọba sọ pe gbogbo ọna ... IDIBO: ORIIRE NLA LO WỌLE TỌ APC NI KWARA - ABDULRAZAQ IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 23, 2024 Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti ba gbogbo awọn oludije to jawe olubori sipo alaga kansu nipinlẹ naa yọ, to si tun ki wọn ku oriire.Lopin ọsẹ to kọja yii ni eto idibo sipo alaga kansu kaakiri ijọba ibilẹ mẹrindinlogun to wa ni Kw... IDIBO 2023 WOO SI I OGUN 2023: ILE-ẸJỌ DA DAPỌ ABIỌDUN LARE, O DOJU ADEBUTU BỌLE L'OGUN IROYIN AWIKONKOBELU 25, 2023 DAPỌ ABIỌDUN DI GOMINA LẸẸKEJI L'OGUN IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 20, 2023 KI TINUBU MA TII YỌ LAYỌJU, OUN PẸLU INEC N TAN ARA WỌN JẸ LASAN NI - ADEBANJỌ, OLORI AFẸNIFẸRE SỌRỌ IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 03, 2023 ỌLỌRUN KO LỌWỌ SI BI TINUBU ṢE FẸẸ DI AARẸ NAIJIRIA, IJAKULẸ NLA NI YOO JÉ F'AWỌN ARAALU - WOLII AYỌDELE IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 03, 2023 NITORI BI WỌN ṢE KEDE TINUBU, IPINLẸ MẸFA GBE IJỌBA APAPỌ LỌ SILE ẸJỌ IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 03, 2023 EMI KO GBA ESI IBO TO GBE APC WỌLE FUN IPO AṢOFIN AGBA N'IPINLẸ OGUN - ADERINOKUN PARIWO SITA IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 02, 2023 SUNDAY ÌGBÒHO WOO SI I O TAN O! ILE ẸJỌ YẸYẸ SUNDAY IGBOHO IROYIN AWIKONKOOKU 30, 2022 AṢIṢE NLA TI MO ṢE REE L'ỌJỌ TI WỌN MU MI NI KUTỌNU - IGBOHO KỌMINU IROYIN AWIKONKOOKUDU 26, 2022 ÌDÍ PÀTÀKÌ TÍ WỌ́N ṢE FI SUNDAY ÌGBÒHO SÍLẸ̀ GAN-AN RÈÉ IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 07, 2022 WỌN TI TU ÌGBÒHO SÍLẸ̀ OOOOOOOO IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 07, 2022 WÀHÁLÀ TUNTUN DÉ BÁ ÌGBÒHO, Ọ̀NÀ TÍ WỌ́N TÚN GBÉ Ọ̀RỌ RẸ̀ GBÀ RÈÉ IROYIN AWIKONKOERELE 07, 2022 AWỌN AGBẸKỌYA LAWỌN ṢETAN LATI FOOGUN ABẸNUGỌNGỌ GBE IGBOHO JADE KURO LẸWỌN TO WA IROYIN AWIKONKOERELE 06, 2022 LÁGBO ÀRÍYÁ WOO SI I KASNATY KO ẸGBẸRUN MEJI ARUGBO LỌ WẸ LODO IGBALODE L'ABẸOKUTA IROYIN AWIKONKOỌWARA 12, 2024 KASNATY SUGAR, GBAJUGBAJA SỌRỌSỌRỌ FẸẸ KO AWỌN ARUGBO LỌ WẸ LODO IGBALODE LỌSẸ YII IROYIN AWIKONKOỌWARA 07, 2024 ALAYỌ SINGER TÚ ÀṢÍRÍ NLÁ NÍPA ÀWỌN TÓ PA ÀDÙKẸ́ GOLD IROYIN AWIKONKOOKU 23, 2024 ÀWỌN ‘Ẹ̀GBỌ́N ÀDÚGBÒ’ LU PORTABLE LÁLÙBAMI LÓKO ERÉ, LÓ BÁ BÚ SẸ́KÚN NÍTA GBANGBA IROYIN AWIKONKOOKU 19, 2024 AYẸYẸ ỌJỌ́ ÌBÍ WOO SI I AYẸYẸ ỌJỌ IBI ABDULRAZAQ BA IGBAKEJI RẸ YỌ F'AYẸYẸ ỌJỌ IBI ỌGỌTA ỌDUN IROYIN AWIKONKOOKU 01, 2023 Bi gbogbo awọn eeyan kaakiri agbaye ṣe n ba igbakeji gomina ipinlẹ Kwara, Kayọde Alabi yọ fun ti ayẹyẹ ọjọ ibi ọgọta ọdun to pe loke eepẹ lonii, ọjọ ... ABDULRAZAQ BA ETSU TSARAGI YỌ F'AYẸYẸ ỌJỌ IBI ỌDUN MEJIDINLAADỌRIN IROYIN AWIKONKOAGẸMỌ 26, 2023 ABDULRAZAQ BA BELGORE, AGBA AMOFIN YỌ F'AYẸYẸ ỌJỌ-IBI IROYIN AWIKONKOOKUDU 25, 2023 WOLII AYỌDELE FUN AKỌWE IROYIN RẸ NI MỌTO BỌGINNI, O TUN FI ẸBUN NLA T'AWỌN ALAINI L'ỌRẸ L'EKOO IROYIN AWIKONKOERELE 16, 2023 AYẸYẸ ÀJỌ̀DÚN ỌDÚN KẸTÀDÍNLÁÀÁDỌ́TA TI IGBÁ-KEJÌ GÓMÌNÀ ÌPÍNLẸ̀ ÒGÙN IROYIN AWIKONKOṢẸRẸ 09, 2023 KÀYÉÉFÌ WOO SI I KAYEEFI AYE O! WỌN YINBỌN PA OLUDIJE SIPO KANSẸLỌ NILE PARAGA L'ABẸOKUTA IROYIN AWIKONKOỌWARA 12, 2024 Niṣe lọrọ di boolọ o yago lọna lonii, ọjọ Abamẹta nigba ti awọn kan tẹnikẹni ko mọ yinbọn pa ọkan lara awọn oludije sipo kansẹlọ niluu Abẹokuta.Adelek... ABDULRAZAQ KẸDUN IKU AWỌN TO KAGBAKO NINU IJAMBA ORI OMI IROYIN AWIKONKOỌWARA 02, 2024 ỌMỌ 'YAHOO' MẸRINLELOGUN HA SỌWỌ EFCC L'ẸDO IROYIN AWIKONKOỌWARA 02, 2024 Ó MÀ ṢE O! ÈÉFÍN JẸNẸRÉTỌ̀ PA IKECHUKWU MỌ́LÉ L'OGUN IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 23, 2024 ỌWỌ AMỌTẸKUN TẸ YAKUBU TO FIPA JA IBALE ỌMỌ ỌDUN MẸWAA L'EKITI IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 19, 2024 KÓÒTÙ WOO SI I KAYEEFI RASHEED JI MỌTO GBE L'ABUJA, IBADAN LỌWỌ TI TẸ Ẹ, L'ADAJỌ BA SỌ PE YOO ṢỌDUN LẸWỌN KO TO GBA IDAJỌ LỌDUN 2024 IROYIN AWIKONKOỌPẸ 18, 2023 Ile-ẹjọ Dei-Dei Grade 1 to wa niluu Abuja ti sọ pe ki derẹba, ẹni ọdun mẹrinlelọgbọn, Ridioam Rasheed ṣi lọ maa gbatẹgun lọgba ẹwọn lori ẹsun wi pe o ... ẸGBẸ AWỌN OṢIṢẸ KOOTU DAṢẸ SILẸ L'ỌṢUN IROYIN AWIKONKOBELU 22, 2023 Ẹ WOJU AWỌN MẸTA TI WỌN TI BA AWỌN ỌMỌ KEEKEEKE LAṢEPỌ L'EKOO IROYIN AWIKONKOEBIBI 02, 2023 NITORI ẸSUN IJINIGBE, WỌN DAJỌ IKU FUN ỌRẸ MẸRIN L'EKOO IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 24, 2023 O PARI! WỌN JU ABURO IYAWO AARẸ ỌBASANJỌ TẸLẸ SẸWỌN ỌDUN MEJE LORI ẸSUN JIBITI IROYIN AWIKONKOERELE 19, 2023 ERÉ ÌDÁRAYÁ WOO SI I ERE IDARAYA ITARA TI MO NI FUN ERE BỌỌLU KO LE YI PADA - JURGEN KLOPP IROYIN AWIKONKOỌWARA 09, 2024 Akọnimọ-ọn-gba ẹgbẹ agbabọọlu Liverpool tẹlẹ, Jurgen Klopp ti sọ pe ko si nnkan to le mu ki itara toun ni fun ere bọọlu lagbaye yipada, pẹlu bo ṣe gba... ÌDÍJE ERÉ ÌDÁRAYÁ ILÉ-IṢẸ́ ADRON HOMES GBỌ̀NÀ ÀRÀ YỌ PẸ̀LÚ DANIEL AMOKACHI ÀTI MUTIU ADEPỌJU IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 19, 2024 ÌJỌBA KWARA ṢE ÌLÉRÍ ÌRÀNLỌ́WỌ́ TUNTUN FÀWỌN Ọ̀DỌ́, LẸ́YÌN ÀṢEYỌRÍ ẸNIỌLA LÁGBAYÉ IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 09, 2024 Ẹ WO BỌ́LÁJÍ ẸNIỌLÁ TÓ FI ÌTÀN TUNTUN BALẸ̀ GẸ́GẸ́ BÍI ỌMỌ ILẸ̀ ÁFRÍKÀ ÀKỌ́KỌ́ TÍ YÓÒ GBA ÀMÌ Ẹ̀YẸ PARALYMPIC NÍNÚ ÌDÍJE BADMINTON IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 03, 2024 LOOKMAN LỌ́PỌLỌ BỌ́Ọ̀LÙ JU OSIMHEN LỌ - PESEIRO SỌRỌ IROYIN AWIKONKOOKU 24, 2024 AWỌN IROYIN AIPẸ WOO SI I Adnaira[N]x SATURDAY, OCTOBER 19, 2024 ELERIN TILUU ERIN-ILE GBỌPA AṢẸ NI KWARA Kwara IROYIN AWIKONKO 5 days ago 0 Elerin tiluu Erin-Ile nipinlẹ Kwara, Ọba Adesoye Adebọwale Jimọh ti gbọpa aṣẹ ati iwe ẹri.Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lo gbe ọpa aṣẹ ati iwe ẹri le Ọba Adesoye Jimọh lọwọ lonii, ọjọ Abamẹta tii ṣe Satide, ọjọ kọkandinlogun, oṣu kẹwaa, ọdun 2024.G... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/19/2024 02:42:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: Kwara IJỌBA KWARA BẸRẸ DIDA ỌDA IKẸYIN SI OPOPONA POST OFFICE, ỌJA ỌBA SI ẸMIR Kwara IROYIN AWIKONKO 5 days ago 0 Lasiko ti a pari akojọpọ iroyin yii, awọn agbaṣẹṣe ti bẹrẹ sii da ọda to kẹyin si opopona Post Office, Ọja Ọba titi de Emir niluu Ilọrin, iyẹn nibi ti akanṣe iṣẹ ti n lọ lọwọ.Ninu atẹjade ti amugbalẹgbẹ agba pataki fun gomina lori eto iroyin igbalo... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/19/2024 01:13:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: Kwara OJULOWO OPOPONA TO JA GEERE NI ỌNA ABAYỌ SI ETO ỌRỌ AJE TO DARA - IJỌBA KWARA Kwara IROYIN AWIKONKO 5 days ago 0 Ijọba ipinlẹ ti ṣe ileri wi pe gbogbo awọn opopona to wa kaakiri ipinlẹ naa ni wọn yoo ṣe ni ti igbalode fun lilo ọjọ pipẹ ti yoo maa mu eto ọrọ aje lọ soke.Kọmiṣanna f'ọrọ iṣẹ ode ati igbokegbodo ọkọ, Onimọ-ẹrọ Abdulquawiy Olododo lo sọ eyi di mim... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/19/2024 01:05:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: Kwara THURSDAY, OCTOBER 17, 2024 ILEEṢẸ ADRON HOMES ṢAFIHAN 'LEMON FRIDAY' PẸLU ANFAANI ALARAGBAYIDA FUN ANFAANI MẸKUNNU Adron Homes IROYIN AWIKONKO 7 days ago 0 Ileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited ti ṣfihan agbekalẹ ọtun fun igbadun araalu, paapaa awọn onibara wọn, eyi ti wọn pe ni '2024 Lemon Friday Promo'.Anfaani ọtun alaragbayida ti ko wọpọ leyi jẹ pẹlu bi ileeṣẹ Adron Homes ṣe kede adinku ati sis... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/17/2024 09:54:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: Adron, Adron Homes OUNJẸ YANTURU NI KWARA, IRỌRUN ỌMỌ NAIJIRIA ISE AGBE IROYIN AWIKONKO 7 days ago 0 Pẹlu bi nnkan ṣe n lọ bayii, ipinlẹ Kwara ti n wa lara awọn ipinlẹ ti yoo fọkan ọmọ Naijiria balẹ nipa ipese ounjẹ, paapaa irẹsi ti awọn eeyan n jẹ julọ.Ipinlẹ Kwara lasiko yii ti ni ọpọ ilẹ ti wọn fi da oko irẹsi si, ti aabo si wa fun un.Ahere ida... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/17/2024 09:25:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: ISE AGBE IJỌBA KWARA ATI AWỌN ALAKOSO FASITI AL-HIKMAH TỌWỌ BỌWE ADEHUN LORI IDASILẸ ỌSIBITU AWỌN OLUKỌNI Kwara IROYIN AWIKONKO 7 days ago 0 Lojuna lati mu ki imọ ijinlẹ nipa eto ilera dagba soke sii, pẹlu bi eto ilera araalu ṣe jẹ ijọba logun, ijọba ipinlẹ Kwara ti tọwọ bọwe adehun pẹlu awọn alakoso fasiti Al-Hikmah lori idasilẹ ọsibitu awọn olukọni.Ọsibitu awọn olukọni naa ni wọn pe n... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/17/2024 09:12:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: Kwara ẸTỌ KAN NAA NI ỌMỌBINRIN ATI OMOKUNRIN NI, Ẹ DẸKUN ẸYAMẸYA - GOMINA ABDULRAZAQ IROYIN IROYIN AWIKONKO 7 days ago 0 Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti rọ awọn eeyan lati dẹkun iwa ẹlẹyamẹya laarin awọn ọmọkunrin ati ọmọbinrin, ati pe ẹtọ kan naa ni wọn jọ ni lawujọ.Bakan naa ni gomina tun fidi ileri rẹ mulẹ pe ijọba oun yoo tubọ maa ṣe ironilagbara... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/17/2024 08:47:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: IROYIN TUESDAY, OCTOBER 15, 2024 ABDULRAZAQ KẸDUN IKU ALAGBA NDAKENE, AGBA OLOṢELU NI KWARA Kwara IROYIN AWIKONKO 9 days ago 0 Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti kẹdun iku agba oloṣelu nni, Alaaji Abubakar Ndakene, ẹni ti jade laye laipẹ yii.Alaaji Ndakene to jẹ Marafan Shonga lo dagbere faye lẹyin aisan rampẹ, gẹgẹ bi a ṣe gbọ.Ninu atẹjade ti akọwe iroyin gomina, Rafiu Aja... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/15/2024 09:21:00 AM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: Kwara SATURDAY, OCTOBER 12, 2024 AYE O! WỌN YINBỌN PA OLUDIJE SIPO KANSẸLỌ NILE PARAGA L'ABẸOKUTA KAYEEFI IROYIN AWIKONKO 12 days ago 0 Niṣe lọrọ di boolọ o yago lọna lonii, ọjọ Abamẹta nigba ti awọn kan tẹnikẹni ko mọ yinbọn pa ọkan lara awọn oludije sipo kansẹlọ niluu Abẹokuta.Adeleke Adeyinka ni orukọ ọmọkunrin naa, ti wọn lo n dije du ipo kansẹlọ ni wọọdu kẹẹdogun, ijọba ibilẹ ... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/12/2024 02:51:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: KAYEEFI IJỌBA KWARA PIN ẸGBẸRUN MARUN-UN KẸKẸ MARUWA TO N LO INA ẸLẸNTIRIIKI FAWỌN ARAALU Kwara IROYIN AWIKONKO 12 days ago 0 Ijọba ipinlẹ Kwara ti sọ pe ohun ṣetan lati pin Kẹkẹ Maruwa to n lo ina ẹlẹntiriiki fawọn araalu lati fi mu irọrun ba igbokegbodo ọkọ.Awọn Kẹkẹ Maruwa naa ti ko din ni ẹgbẹrun marun-un ni ijọba sọ pe ohun yoo pin fun gbogbo awọn ti wọn mọ nipa rẹ d... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/12/2024 06:30:00 AM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: IROYIN, Kwara KASNATY KO ẸGBẸRUN MEJI ARUGBO LỌ WẸ LODO IGBALODE L'ABẸOKUTA LAGBO ARIYA IROYIN AWIKONKO 12 days ago 0 Ko din ni ẹgbẹrun meji arugbo ti gbajugbaja sọrọsọrọ nni, Kọlawọle Atanda Adejojo ti ọpọ mọ si Kasnaty Sugar ko lọ wẹ lodo igbalode niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun lọjọ kẹwaa, oṣu kẹwaa, ọdun 2024.Pẹlu idunnu ati ayọ ni awọn arugbo ọhun ti ọjọ ori wọn ... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/12/2024 05:57:00 AM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: IROYIN, LAGBO ARIYA FRIDAY, OCTOBER 11, 2024 IPINLẸ KWARA FẸẸ ṢAGBEKALẸ INA MỌNAMỌNA ALADANI Kwara IROYIN AWIKONKO 13 days ago 0 Ijọba ipinlẹ kwara labẹ iṣakoso Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti fidi ileri rẹ mulẹ lati ṣagbekalẹ ina mọnamọna aladani fun ipinlẹ naa, lati maa fi pawo wọle. Ina mọnamọna aladani ọhun ti wọn pe ni independent Power Plant (IPP) ni ijọba Kwara sọ pe... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/11/2024 05:11:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: IROYIN, Kwara THURSDAY, OCTOBER 10, 2024 GOMINA ABDULRAZAQ FI ỌGỌRUN MILIỌNU NAIRA TA AWỌN TO ṢAGBAKO IJAMBA ORI OMI NI KAIAMA LỌRẸ Kwara IROYIN AWIKONKO 14 days ago 0 Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti kede ọgọrun kan naira gẹgẹ bi owo iranwọ fun awọn to fara kaasa ninu ijamba ori omi ni Kaiama.Awọn eeyan to to igba la gbọ pe wọn ni ijamba ninu ọkọ oju omi ọhun lati ijọba ibilẹ Kaiama.Oni, Ọjọbọ ni... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/10/2024 08:38:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: Kwara WEDNESDAY, OCTOBER 9, 2024 BI GOMINA ABDULRAZAQ ṢE MU ETO ILERA LỌKUNKUNDUN JẸ OHUN IWURI NLA - EMIR ILỌRIN Kwara IROYIN AWIKONKO 15 days ago 0 Emir ilu Ilọrin, Ọmọwe Ibrahim Zulu-Gambari ti gbe oṣuba kare fun Gomin AbdulRahman AbdulRazaq lori bo ti ṣe mu eto ilera lọkunkundun, fun awọn ara ipinlẹ Kwara.Ọmọwe Zulu-Gambari lo sọ eyi nibi ifilọlẹ ipolongo eto ilera ti wọn pe ni Project 10 M... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/09/2024 01:44:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: ILERA, Kwara NNPC KEDE AFIKUN OWO ORI JAALA EPO IROYIN IROYIN AWIKONKO 15 days ago 0 Ajọ to n ṣabojuto epo rọbii lorileede Naijiria, Nigerian National Petroleum Company Limited, NNPCL ti kede afikun lori owo ori jaala epo bẹntiroolu kaakiri ilẹ yii. NNPC sọ pe ẹgbẹkan le ni ọgbọn naira, N1,030 ni awọn yoo maa ta jaala epo bẹntirool... KAA SIWAJU SII By IROYIN AWIKONKO at 10/09/2024 01:12:00 PM No comments: Email ThisBlogThis!Share to TwitterShare to FacebookShare to Pinterest Tags: IROYIN Page 1 of 93912345...939Next �Last Adnaira[N]x PÍN-IN KÁÀKIRI AUTHOR DETAILS ỌRỌ̀ AJÉ WOO SI I ỌBASANJỌ NI KI IJỌBA NAIJIRIA LỌ GBA AMỌRAN LORI ETO ỌRỌ AJE TO DORIKODO NI ZIMBABWE IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 05, 2024 Aarẹ tẹlẹri Naijiria, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ ti gba ijọba orileede yii lamọran lati lọ gba amọran l... ILE IGBIMỌ AṢOJU-ṢOFIN PAṢẸ KI WỌN LỌ FI KELE OFIN GBE AWỌN ALAKOSO BINACE IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 04, 2024 Ile igbimọ aṣoju-ṣofin Naijiria ti paṣẹ pe ki awọon agbofinro lọ gbe awọn alakoso ileeṣẹ paṣipaarọ o... TINUBU KII ṢE ONIDAN LATI WA OJUTU SỌNA ABAYỌ ETO ỌRỌ AJE NAIJIRIA TO FORI ṢANPỌN - WOLII AYỌDELE IROYIN AWIKONKOERELE 26, 2024 Alaṣẹ ati olori ijọ INRI Evangelical Spiritual Church, Wolii Elijah Ayọdele ti sọ pe ko si idan kank... LÁWÙJỌ WA WOO SI I LIṢABI: ALAKE FẸẸ DA MACGREGOR, OLU ORILE-ILAWỌ TI WỌN ṢẸṢẸ YAN LỌLA L'ABẸOKUTA IROYIN AWIKONKOERELE 16, 2023 Gbogbo eto lo ti pari patapapta bayii fun Alakẹ ilẹ Ẹgba, Ọba Adedọtun Arẹmnu Gbadebọ lati fi ẹbun n... ILU-MỌ-ỌN-KA PEDEPEDE, IDOWU TAIWO DI AṢOJU ILEEṢẸ ‘IDGE MERIT PROPERTIES’ TO N ṢOWO ILẸ IROYIN AWIKONKOOKUDU 20, 2022 Bọsun Ọlaniyi, AbẹokutaOrin ọpẹ l’awọn ololufẹ gbajugbaja pedepede nni, Idowu Taiwo ti ọpọ awọn eeya... ITAN ṢOKI NIPA 'ỌMỌ ENIYAN' TI MO GBỌ LẸNU ỌBASANJỌ DABI PE MO WA NI YARA IKẸKỌỌ - KẸMI ADEỌṢUN IROYIN AWIKONKOEBIBI 02, 2022 Minisita f'ọrọ eto iṣuna tẹlẹri lorileede Naijiria, Arabinrin Oluwakẹmi Adeọṣun ti sọ pe asiko peret... KỌ́MILẸ́KỌ̀Ọ́: ÈYÍ NI ORÚKỌ ÀWỌN ẸRANKO ÀGBÁYÉ NI ÈDÈ ÒYÌNBÓ ÀTI YORÙBÁ IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 07, 2022 Ọpọ awọn eeyan ni wọn mọ orukọ ẹyẹ ati ẹranko lede Oyinbo, ṣugbọn ti wọn ko mọ itumọ wọn lede Yoruba... ỌỌ̀NI ILÉ-IFẸ̀, ỌBA ÒGÚNWÙSÌ GBOYÈ Ọ̀MỌ̀WÉ NÍ FÁSITÌ ABUAD IROYIN AWIKONKOBELU 26, 2021 Ọọni Ile-Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi naa ti wa lara awọn agba ọba alaye ti wọn gboye Ọmọwe bay... AKỌNI TÍTÍ LÁÍ NI LAWAL JẸ́ FÁWỌN ÈÈYÀN ÌPÍNLẸ̀ KWARA - GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ IROYIN AWIKONKOBELU 15, 2021 Gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq ti sọ pe titi lai ni gomina tẹlẹri nipinlẹ naa, Oloogbe... FÍDÍÒ WOO SI I O ṢẸLẸ! Ẹ GBỌ NNKAN TI BUHARI ỌMỌ MUSA SỌ NIPA GOMINA ABDULRAZAQ T'IPINLẸ KWARA IROYIN AWIKONKOOKUDU 16, 2020 Ẹ WO ṢỌJA TO ṢE AYẸTA IBỌN, BO ṢE N GBE E JẸ NI KO KU IROYIN AWIKONKOAGẸMỌ 25, 2019 FIDIO ṢANAWỌLE, OGBOLOGBO ỌMỌDUN MỌKANLA TO N ṢE ẸGBẸ OKUNKUN IROYIN AWIKONKOOKUDU 09, 2019 ALABI YELLOW NILO IRANLỌWỌ GIDIGIDI IROYIN AWIKONKOẸRẸNA 26, 2019 Ẹ GBỌ NNKAN TI GOMINA AJIMỌBI TUN SỌ O IROYIN AWIKONKOERELE 26, 2019 WAHALA DE; AKINLADE BU ẸNU ATẸ LU IJỌBA AMOSUN IROYIN AWIKONKOERELE 08, 2019 ÌLERA WOO SI I BI GOMINA ABDULRAZAQ ṢE MU ETO ILERA LỌKUNKUNDUN JẸ OHUN IWURI NLA - EMIR ILỌRIN IROYIN AWIKONKOỌWARA 09, 2024 ỌBA MACGREGOR KỌ́ ILÉ ÌWÒSÀN ALÁBỌ́DÉ ÀWÒṢÍFÌLÀ SÍLÙÚ ẸLẸ́GUNMẸ́FÀ (FỌTO) IROYIN AWIKONKOỌWẸWẸ 12, 2024 'Ó DÁ MI LÓJÚ PÉ Ẹ MÁA TAYỌ LẸ́KA ÈTÒ ÌLERA LÁGBAYÉ - ABDULRAZAQ SỌ FÁWỌN AKẸ́KỌ̀Ọ́JÁDE ILÉ Ẹ̀KỌ́ ÈTÒ ÌLERA IROYIN AWIKONKOOKU 25, 2024 ÌDÌBÒ WOO SI I A RÒ BÍ OGUN MÁA ṢẸLẸ̀ L'Ọ́ṢUN NI, ṢÙGBỌ́N... - ABDULRAZAQ IROYIN AWIKONKOERELE 19, 2022 SOLUDO GBA ÌWÉ Ẹ̀RÍ 'MOYEGE' LỌ́WỌ́ ÀJỌ INEC GẸ́GẸ́ BÍI GÓMÌNÀ TUNTUN L'ANAMBRA IROYIN AWIKONKOBELU 14, 2021 INEC KÉDE SOLUDO GẸ́GẸ́ BÍ GÓMÌNÀ ÌPÍNLẸ̀ ANAMBRA TUNTUN IROYIN AWIKONKOBELU 10, 2021 ÌKÀNNÌ AYÉLUJÁRA WA * Likes * Followers * Subscribes * Followers * Followers TUNTUN REE LORI IGBA ÀWỌN TÓ Ń KA AWÍKONKO 091521131246586137208119710101191281371418157167171001847191320921822102310241625192624271528182915 7126765 LÓRÍ WHATSAPP OWÓ ÀGBÁYÉ Owo Paṣipaarọ USD - United States dollar $ EUR - Euro € GBP - British pound £ JPY - Japanese yen ¥ CNY - Chinese yuan ¥ USD - United States dollar $ i October 24, 2024 17:30:03 FreeCurrencyRates.com Ẹ TẸ̀LÉ WA LÓRÍ FACEBOOK Ẹ TẸ̀LÉ WA LÓRÍ TWITTER AWIKONKO. Powered by Blogger. * ÌRÒYÌN * GBAJÚMỌ̀ * ÈSÌ ELERIN TILUU ERIN-ILE GBỌPA AṢẸ NI KWARA IROYIN AWIKONKOỌWARA 19, 2024 IJỌBA KWARA BẸRẸ DIDA ỌDA IKẸYIN SI OPOPONA POST OFFICE, ỌJA ỌBA SI ẸMIR IROYIN AWIKONKOỌWARA 19, 2024 OJULOWO OPOPONA TO JA GEERE NI ỌNA ABAYỌ SI ETO ỌRỌ AJE TO DARA - IJỌBA KWARA IROYIN AWIKONKOỌWARA 19, 2024 ILEEṢẸ ADRON HOMES ṢAFIHAN 'LEMON FRIDAY' PẸLU ANFAANI ALARAGBAYIDA FUN ANFAANI MẸKUNNU IROYIN AWIKONKOỌWARA 17, 2024 OUNJẸ YANTURU NI KWARA, IRỌRUN ỌMỌ NAIJIRIA IROYIN AWIKONKOỌWARA 17, 2024 * Aye o! Wọn yinbọn pa oludije sipo kansẹlọ nile paraga l'Abẹokuta Niṣe lọrọ di boolọ o yago lọna lonii, ọjọ Abamẹta nigba ti awọn kan tẹnikẹni ko mọ yinbọn pa ọkan lara awọn oludije sipo kansẹlọ niluu Abẹok... * Ijọba Kwara pin ẹgbẹrun marun-un Kẹkẹ Maruwa to n lo ina ẹlẹntiriiki fawọn araalu Ijọba ipinlẹ Kwara ti sọ pe ohun ṣetan lati pin Kẹkẹ Maruwa to n lo ina ẹlẹntiriiki fawọn araalu lati fi mu irọrun ba igbokegbodo ọkọ. Awọn ... * Aye o! Wọn yinbọn fun gbajumọ olorin Fuji nibi to ti lọ kọrin l'Abẹokuta Titi di asiko ti a pari akojọpọ iroyin yii, ẹbẹ iranlọwọ ni gbajugbaja olorin Fuji nni, Bọlọmọpe Saheed Akangbe ti gbogbo eeyan mọ si Landom... * Ronaldo yoo ṣi wa pẹlu wa fun saa to n bọ - Al Nassr Alaṣẹ ẹgbẹ Al Nassr nilẹ Saudi Arabia, Guido Fienga ti sọ pe ogbontarigi agbabọọlu nni, Cristiano Ronaldo yoo ṣi wa pẹlu wọn fun saa to n b... * Nicki Minaj dero atimọle ni Netherlands, wọn lo gbe egboogi oloro Gbajugbaja onkọrin ilẹ Amẹrika nni, Nicky Minaj lo ti dero atimọle ni papakọ ofurufu ti Amsterdam Schiphol lori ẹsun wi pe wọn fura sii pe o... Anonymous"Thought our governor really try but we are just ap..." Anonymous"I want to be part of this job " Anonymous"A ku ara fera ku o. Oruko Fadeyi kole parun lagbo ..." Anonymous"Ẹ kú oríire, ọ̀gáà mi. May Allah bless you abundantly. " Anonymous"Mr layi Mohammed, you and your family we safer at ..." Adnaira[N]x POLÓWÓ PẸ̀LU WA https://adronhomesproperties.com/ ÌFỌ̀RỌ̀WÉRỌ̀ BI MO ṢE PADANU KII ṢOJU LASAN, O LỌWỌ OṢELU NINU - SARAKI PARIWO SITA IROYIN AWIKONKOERELE 26, 2019 OṢELU NAIJIRIA KO GBA GIDIGBO - ỌMỌBA ỌRUN IROYIN AWIKONKOERELE 04, 2019 Ẹ GBỌ́ KÍ LÈ RÍ SÍ I ?: ÀWỌN ONÍMỌ̀ NÍ ÀWỌN OBÌNRIN TÍ Ó GA TÍ WỌN Ò SÌ SANRA NÍ ÀǸFÀNÍ SÍ Ẹ̀MÍ GÍGÙN JU ÀWỌN ÌYÓKÙ LỌ UnknownṢẸRẸ 24, 2019 EEMETA OTOOTO NI MO SA KURO NINU SOOSI SELE, CCC - KUNLE HAMILTON IROYIN AWIKONKOBELU 21, 2018 MI O LE GBAGBE OJO TI MO GBE MAJELE JE - OGUNWOOLU IROYIN AWIKONKOỌWARA 08, 2018 Ẹ̀KA ÌRÒYÌN WA #ENDSARS Adron Adron Homes AGBA WA BURA AJORO AMERIKA Amọtẹkun Asa ati Isese Asọtẹlẹ AYAJỌ OLOLUFẸ AYẸYẸ ỌJỌ IBI Baba Egun Aworawọ BBC CBN CORONAVIRUS EFCC ERE IDARAYA Esin Eto Aabo Eto Eko ETO IDAJỌ Eto Isuna FIBAN FIDIO Fiimu Agbelewo Fọto FỌTO ARAMBARA FUNKE ANIMASAUN IBEERE IDAGBASOKE IDIBO Idibo 2023 IFOROWERO IGBEYAWO ILERA ILEYA Imọtoto INEC IPOLOWO Irin Ajo Afẹ IROYIN ISE AGBE JAMB June 12 K'Ade Pẹ Lori KANSELO KAYEEFI KERESIMESI KÉRÉSÌMESÌ Kọ́milẹ́kọ̀ọ́ KOOTU KORONAFAIRỌỌSI Kwara LAGBO ARIYA law LAWUJO AKONI LAWUJO WA Liṣabi MFM NANB NGIJ NLC NURTW ỌDARAN OJUDE OBA OLUWA MI Ominira OMPAN OPC ORO AJE ORO SUNNUKUN ORO TO N LO Oselu Oṣiṣẹ Òṣìṣẹ́ Owó Oṣù Tuntun Pelican RAMADAANI SO-SAFE Sunday Igboho SWEET ESTATE YCYW YYC Ẹ JẸ́ KÁ GBÉ ÒṢÙBÀ FÚN AWÍKONKO * Nipa Wa * Ilepa ati Afojusun * Ẹ ba wa dele * Iroyin Tuntun * AWỌN OṢIṢẸ WA * IBEERE * IPOLOWO * IKEDE PATAKI MenuNIPA WAILEPA ATI AFOJUSUNẸ BA WA DELEIROYIN TUNTUNAWỌN OṢIṢẸ WAIBEEREIPOLOWOIKEDE PATAKI * * * * * * LÁWÙJỌ AKỌNI ÌṢỌ̀LÁ SAUBAN ÀLÀDÉ ORÍ-ÀRÁN DI Ọ̀MỌ̀WÉ TUNTUN NÍNÚ ÌMỌ̀-ÌJÌNLẸ̀ YORÙBÁ IROYIN AWIKONKOERELE 23, 2023 Ẹ WO AWỌN PATA FẸLA ANIKULAPO TI WỌN N FI OWO WO LORILEEDE FRANCE IROYIN AWIKONKOERELE 14, 2023 BỌ́ÌSÌ ṢÌ NI MÍ - OLÚWÒÓ TI ÌLÚ ÌWÓ L'Ọ́ṢUN IROYIN AWIKONKOAGẸMỌ 04, 2022 AMBASIDỌ RERE NI KUNLE ADEYANJU JẸ - ABDULRAZAQ IROYIN AWIKONKOEBIBI 31, 2022 ỌỌ̀NI ILÉ-IFẸ̀, ỌBA ÒGÚNWÙSÌ GBOYÈ Ọ̀MỌ̀WÉ NÍ FÁSITÌ ABUAD IROYIN AWIKONKOBELU 26, 2021 Ọ̀RỌ̀ ṢÙNNÙKÙN Ọ̀NÀ ÀBÁYỌ SÍ ÀWỌN ÌṢÒRO ILẸ̀ NÀÌJÍRÍÀ RÈÉ IROYIN AWIKONKOERELE 03, 2023 BÍ A BÁ NÍ SÙÚRÙ, TÍ A SÌ KÚN FÚN ÁDÙRÁ, DANDAN NI KÍ NÀÌJÍRÍÀ YÌÍ PADÀ KÚRÒ NÍNÚ ÌṢÒRO RẸ̀ IROYIN AWIKONKOERELE 02, 2023 ÌMỌ̀RÀN FÚN GBOGBO OLÙDÌBÒ NÍLẸ̀ YORÙBÁ IROYIN AWIKONKOERELE 01, 2023 ÀWỌN OHUN TÍ Ń DA NÀÌJÍRÍÀ LÁÀMÚ GAN-AN NÌYÍ IROYIN AWIKONKOṢẸRẸ 31, 2023 IFIPABANILOPO: AARUN TO GBODE IROYIN AWIKONKOBELU 24, 2018 ÀJỌRỌ̀ ILẸ̀ N YỌ̀ UnknownOKUDU 18, 2019 IWA OMOLUABI DA LAWUJO WA? IROYIN AWIKONKOỌWARA 27, 2018 BAWO LO SE N LO FOONU ALAGBEKA IGBALODE? IROYIN AWIKONKOỌWARA 20, 2018 KI LO SE OMO YORUBA PELU KEMI ADEOSUN? IROYIN AWIKONKOAGẸMỌ 15, 2018 TA NI FULANI DARAN-DARAN?? IROYIN AWIKONKOAGẸMỌ 06, 2018 Copyright © 2024 IROYIN AWIKONKO CONTACT FORM Name Email * Message * Deze site gebruikt cookies van Google om services te leveren en verkeer te analyseren. Je IP-adres en user-agent worden met Google gedeeld, samen met prestatie- en beveiligingsstatistieken om servicekwaliteit te garanderen, gebruiksstatistieken te genereren, misbruik te detecteren en maatregelen te treffen.Meer informatieIk snap het